Págà! A kò rí oun tó jọ "Ará"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Arábámbí
Meaning: Family/kin joined to give birth to this.
Arádéyọ̀
Meaning: We found royalty and rejoiced.
Arájùlù
Meaning: Kin is greater than the town.
Arálamọ̀
Meaning: We only know kin.
Arálọlá
Meaning: Family/kin is one's honor.
Arámìdé
Meaning: 1. My company, kin, or relative, has come. (Arámìdé) 2. My wonder has come (Àràmídé)
Aránmọ̀látẹ̀
Meaning: We've sent the child to (sell at) the market.
Aranse
Meaning: [unknown]
Aráolúwa
Meaning: 1. The lord's kin (Aráolúwa) 2. The lord's wonder (Àràolúwa)
Aráoyè
Meaning: The kin of nobility.
Arápájà
Meaning: One with arms competent to fight.
Arápáregángan
Meaning: One with arms competent enough to dance to the gángan drums.
Arárọ̀mí
Meaning: I am relieved.
Arárónkẹ́
Meaning: Family has found one to cherish.
Aráwọlé
Meaning: Kinfolk have entered.