Akíntọ̀mídé
Sísọ síta
Ìtumọọ Akíntọ̀mídé
Valor/Bravery finds me.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Akíntọ̀míwá
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-tọ̀-mí-dé, tọ̀dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, the hero, the brave onetọ̀ - to trail, to search, to follow
mí - me
dé - to arrive
tọ̀dé - to seek, to trail/find
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS