Akíndélé
Sísọ síta
Ìtumọọ Akíndélé
1. Valor has arrived home. 2. The brave one has returned home.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
akin-dé-ilé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
akin - valor, bravery, heroism, the brave onedé - arrive, return
ilé - house, home
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
