Ajíbọ́lọ́runsọ̀rọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ajíbọ́lọ́runsọ̀rọ̀

The one who wakes up and speaks with God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-jí-bá-ọlọ́run-sọ̀rọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
- to wake up
- meet, join
ọlọ́run - God
sọ̀rọ̀ - to talk


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL