Agbélékalẹ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Agbélékalẹ̀

The builder.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-gbé-ilé-kalẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - someone
gbé...kalẹ̀ - erect, site
ilé - house


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL