Adémúwàgún
Sísọ síta
Ìtumọọ Adémúwàgún
The crown aligns character.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-mú-ùwà-gún
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crown, royaltymú - hold onto, pick, make
ùwà - character (ìwà)
gún - be proper, be appropriate, be just
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
EKITI                    
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
- Professor Zacchaeus Akingbade Ademuwagun Oba Ademuwagun Adesida II 
- Deji of Akure (1957-1973) 
