Adéríbigbé
Sísọ síta
Ìtumọọ Adéríbigbé
The crown has found a place to live.
Àwọn àlàyé mìíràn
See also: Adéríbidó
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
adé-rí-ibi-gbé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
adé - crownrí - see, find
ibi - somewhere
gbé - live
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Oyínkánsọ́lá Sarah Adéríbigbé. Nigerian musician
also known as 'Ayra Starr'.