Adéṣẹ́gun

Sísọ síta



Ìtumọọ Adéṣẹ́gun

The crown is victorious.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-ṣẹ́-ogun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
ṣé - end, break
ogun - war, quarrel, acrimony
ṣẹ́gun - conquer


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ṣẹ́gun