Adékìńtẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Adékìńtẹ́

The crown does not get in trouble.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-kìí-ń-tẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
kìí - does not, never
ń - continue to
tẹ́ - to be disgraced; to be in trouble


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adékìíńtẹ́

Adékìítẹ́

Kìńtẹ́

Kìítẹ́