Adarálèṣù

Sísọ síta



Ìtumọọ Adarálèṣù

One who becomes a relative of Èṣù.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

a-di-ará-ni-èṣù



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

a - one who
di - becomes
ará - family, relative
ni - in, of
èṣù - god of trickery and messengers


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Darálèṣù