Adémijùwọ́nlọ

Sísọ síta



Ìtumọọ Adémijùwọ́nlọ

My crown is greater than them.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

adé-mi-jùlọ-wọ́n



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

adé - crown, royalty
mi - me
jùlọ - more than
wọ́n - them


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IFE



Irúurú

Adémijùwọ́n

Adéjùwọ́n