Àṣàbíadé

Sísọ síta



Ìtumọọ Àṣàbíadé

Royally selected for birth.



Àwọn àlàyé mìíràn

A cognomen, oríkì



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

à-ṣà-bí-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

à - we/one who
ṣà - selecting
- give birth to
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI