Ọmọ́bóyèdé
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọmọ́bóyèdé
The child has arrived with a chieftaincy title.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọmọ-bá-oyè-dé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọmọ - childbá - together with
oyè - chieftaincy, honour
dé - come, arrive
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL