Ọláyẹrí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọláyẹrí

Honor befits the head.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-yẹ-orí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - honour, prestige, wealth, nobility
yẹ - to befit, to suit me, to be worthy of
orí - head, body


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Yẹrí