Ọlábàmerun

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọlábàmerun

The prestige of my lineage isn't lost.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-bà-me-è-run



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - prestige, nobility, success
bà - father (bàbá)
me - my, mine
- has not
run - ruin


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO