Ọlọ́fínbínú
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọlọ́fínbínú
Ọlọ́fin is not angry (at us).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlọ́fin-ò-bínú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlọ́fin - Ọlọ́fin, deified ancestral god-king of many towns; king, royal oneò - is not, does not
bínú - be angry
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO