Ọdẹ́níhún
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọdẹ́níhún
The hunter has something to be excited about.
Àwọn àlàyé mìíràn
More properly written as Ọdẹ́níihún.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọdẹ-ní-i-hún
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọdẹ - hunterní - to have, own
i - that who; that which; thing
hún - become agitated or excited, celebrate
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OSUN
OYO