Ọbájẹ́nyọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ọbájẹ́nyọ̀

The king has made me rejoice.



Àwọn àlàyé mìíràn

See: Olújẹ́nyọ̀, Adéjẹ́nyọ̀, etc



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọba-jẹ́-n-yọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọba - king, ruler; Ọbalúayé, the god of disease and healing
jẹ́ - permit, to exist, to be effective
n - me
yọ̀ - rejoice


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Jẹ́nyọ̀