Ọbáfúnmiláyọ̀
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọbáfúnmiláyọ̀
The king gave me joy.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọba-fún-mi-ní-ayọ̀
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọba - king, ruler; Ọbalúayé, the god of disease and healingfún - to give to
mi - me, my
ní - have, own; in
ayọ̀ - joy
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA