Ọ̀ráfidódò
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ráfidódò
The god Ọ̀ràm̀fẹ̀ used (this child) to block the river?
Àwọn àlàyé mìíràn
See Elúfidódò, Ògúnfidódò, etc
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀rà-fi-dí-odò
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀rà - Ọ̀ràm̀fẹ̀, the ancient Ifẹ̀ deity of fire, kingship, and jurisprudencefi - use, put
dí - to block
odò - river
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IFE