Ọ̀ṣúntinúbú
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀ṣúntinúbú
Ọ̀ṣun came from within the deep waters.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀ṣun-ti-inú-ibú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀ṣun - Yorùbá river goddess of fertility and beautyti - has; from
inú - stomach, inside, heart
ibú - deep (ocean)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Ẹfúnróyè (Ọ̀ṣún)Tinúbú
one of the most powerful 19th century women in pre-colonial Yorubaland