Ẹwàolúwaborí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹwàolúwaborí

God's beauty surpasses all.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹwà-olúwa-borí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹwà - beauty
olúwa - God, Lord
borí - to conquer


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ẹwàolúwa