Ẹlẹ́kọ̀lé

Pronunciation



Meaning of Ẹlẹ́kọ̀lé

The ruler of Ìkọ̀lé.



Morphology

oní-ìkọ̀lé



Gloss

oní - one who owns, the leader of
ìkọ̀lé - Ìkọ̀lé


Geolocation

Common in:
AKURE
EKITI