Ẹgbẹ́làńbẹ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Ẹgbẹ́làńbẹ̀

We are begging the Ẹgbẹ́ spirit.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ẹgbẹ́-ni-à-ń-bẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spirit
ni - is
à - we/one who
ń - continue to
bẹ̀ - beg; plead


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Làńbẹ̀