Ẹgbẹ́fúnmilọ́pẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Ẹgbẹ́fúnmilọ́pẹ́
The Ẹgbẹ́ spirit gave me thanksgiving.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ẹgbẹ́-fún-mi-ní-ọpẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spiritfún - to give to
mi - me
ní - have, own; in
ọpẹ́ - thanksgiving, praise
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA