Ṣewéjẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Ṣewéjẹ́

(One who) prepares the leaves that heal.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

se-ewé-jẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ṣe - make
ewé - leaf, herbs
jẹ́ - be efficacious


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA