Òkédìran
Sísọ síta
Ìtumọọ Òkédìran
The (worship of the) hill deity has become generational.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
òkè-di-ìran
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
òkè - Deity of the mountain; mountain, hill, Òkè Ìbàdàndi - become
ìran - generation(s), genealogy, lineage
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OYO