Ọ̀jẹ́kálú
Sísọ síta
Ìtumọọ Ọ̀jẹ́kálú
The Eégún worshipper is known all over the town.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọ̀jẹ̀-ká-ìlú
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọ̀jẹ̀ - Egúngún (masquerade) worshipper, lineage of masquerade worshipperská - all around (káàkiri)
ìlú - town
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OYO