Ìjáwáre
Sísọ síta
Ìtumọọ Ìjáwáre
Ìja has come with goodness.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ìja-wá-ire
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ìja - Ìja, deity of hunting, brother of Ògún and Ọ̀ṣọ́ọ̀sìwá - to find, to come
ire - goodness
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OWO