Égúnlétí
Sísọ síta
Ìtumọọ Égúnlétí
A variant of Eégúnlétí, the Eégún masquerade has ears (to hear our prayers).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
eégún-ní-etí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
eégún - Egúngún spirit; masquerade figurení - have, own; in
etí - ears
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OYO