Àgbédèyímú
Sísọ síta
Ìtumọọ Àgbédèyímú
Àgbé (Ọ̀sanyìn) held onto this (one).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
àgbé-di...mú, èyí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
àgbé - Ọ̀sanyìn, the Yoruba god of magic and herbal medicinedi...mú - to hold, to hold onto
èyí - this (one)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKITI