Káshìmawò

Sísọ sítaÌtumọọ Káshìmawò

Let's keep observing (this one).Àwọn àlàyé mìíràn

This is a common spelling of an abíkú name "Káṣìmáawòó".Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kí-á-ṣì-máa-wòóÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kí - that
- we
ṣì - still
máa - continue to
wò - look at
- [placeholder for the object noun]


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTAÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Moshood Káṣìmáwò Abíọ́lá, Nigerian politician and acclaimed winner of the June 12 1993 presidential elections.Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

KáṣìmáawòóẸ tún wo