Gbénró

Sísọ sítaÌtumọọ Gbénró

1. Uphold me. 2. Uplift me.Àwọn àlàyé mìíràn

The longer form is Olúgbémiró, or Olúgbénró.Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

gbé-n-róÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

gbé - carry
n - me (mi)
ró - stand (a shortened form of "dúró")


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYOÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Olúgbémiró, Olúgbénró, Olúwagbémiró, Olúwagbénró.Ẹ tún wo