Kòfowórọlá

Sísọ sítaÌtumọọ Kòfowórọlá

This wealth isn't bought.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kò-fi-owó-ra-ọláÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kò - (he/she) didn't
fi - use
owó - money
rà - buy
ọlá - wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
EKOÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀

Kòfowórọlá Bucknor, deputy Governor of Lagos State 1999-2002.Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

KòfóẸ tún wo