Fárónbí

Sísọ sítaÌtumọọ Fárónbí

Ifá has found someone to birth.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)fá-rí-oun-bíÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ifá - Ifá divination/corpus/priesthood
rí - see, find
oun - something, someone
bí - give birth to


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDOÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Fáróunbí, Ifárónbí, IfáróunbíẸ tún wo