Ayọ̀mítúndé

Sísọ sítaÌtumọọ Ayọ̀mítúndé

My joy has returned.Àwọn àlàyé mìírànÌtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ayọ̀-mi-tún-déÌtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ayọ̀ - joy, celebration
mi - me
tún - again
dé - to arrive


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERALÀwọn Ènìyàn Gbajúọ̀Ibi tí a ti lè kà síiIrúurú

Ayọ̀, Túndé, Ayọ̀túndéẸ tún wo